Ẹkisodu 6:9 BM

9 Mose sọ ọ̀rọ̀ wọnyi fún àwọn eniyan Israẹli, ṣugbọn wọn kò fetí sí ohun tí ó ń sọ, nítorí pé ìyà burúkú tí wọn ń jẹ ní oko ẹrú ti jẹ́ kí ọkàn wọn rẹ̀wẹ̀sì.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 6

Wo Ẹkisodu 6:9 ni o tọ