Ẹkisodu 9:10 BM

10 Mose ati Aaroni bá bu eérú ninu ẹbu, wọ́n dúró níwájú Farao. Mose da eérú náà sókè sí ojú ọ̀run, eérú náà bá di oówo tí ń di egbò lára eniyan ati ẹranko.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 9

Wo Ẹkisodu 9:10 ni o tọ