11 Àwọn pidánpidán kò lè dúró níwájú Mose, nítorí pe oówo bo àwọn náà ati gbogbo àwọn eniyan ilẹ̀ Ijipti.
Ka pipe ipin Ẹkisodu 9
Wo Ẹkisodu 9:11 ni o tọ