Jobu 1:15 BM

15 àwọn ará Sabea rí wọn, wọ́n sì kó gbogbo wọn, wọ́n sì fi idà pa gbogbo àwọn iranṣẹ, èmi nìkan ni mo sá àsálà láti wá ròyìn fún ọ.”

Ka pipe ipin Jobu 1

Wo Jobu 1:15 ni o tọ