12 O fún mi ní ìyè,o sì fi ìfẹ́ ńlá rẹ tí kì í yẹ̀ hàn sí mi,ìtọ́jú rẹ sì ti gbé ẹ̀mí mi ró.
Ka pipe ipin Jobu 10
Wo Jobu 10:12 ni o tọ