Jobu 11:3 BM

3 Ṣé o rò pé ìsọkúsọ rẹ lè pa eniyan lẹ́nu mọ́ ni?Tabi pé bí o bá ń ṣe ẹlẹ́yà ẹnikẹ́ni kò lè dójútì ọ́?

Ka pipe ipin Jobu 11

Wo Jobu 11:3 ni o tọ