Jobu 12:24 BM

24 Ó gba ìmọ̀ kúrò lọ́wọ́ àwọn ìjòyè ní gbogbo ayé,ó sì sọ wọ́n di alárìnká ninu aṣálẹ̀,níbi tí ọ̀nà kò sí.

Ka pipe ipin Jobu 12

Wo Jobu 12:24 ni o tọ