13 Ìbá sàn kí o fi mí pamọ́ sinu ibojì,kí o pa mí mọ́ títí inú rẹ yóo fi rọ̀,ò bá dá àkókò fún mi, kí o sì ranti mi.
Ka pipe ipin Jobu 14
Wo Jobu 14:13 ni o tọ