Jobu 17:5 BM

5 Bí ẹnìkan bá hùwà ọ̀dàlẹ̀, tí ó ṣòfófó àwọn ọ̀rẹ́,kí ó lè pín ninu ohun ìní wọn,àwọn ọmọ olúwarẹ̀ yóo jìyà.

Ka pipe ipin Jobu 17

Wo Jobu 17:5 ni o tọ