Jobu 20:10 BM

10 Àwọn ọmọ rẹ̀ yóo máa wá ojurere àwọn aláìní,wọn yóo sì san ohun tí baba wọn gbà lọ́wọ́ aláìní pada.

Ka pipe ipin Jobu 20

Wo Jobu 20:10 ni o tọ