Jobu 27:14 BM

14 Bí àwọn ọmọ rẹ̀ bá ń pọ̀ sí i,kí ogun baà lè pa wọ́n ni,oúnjẹ kò sì ní ká wọn lẹ́nu.

Ka pipe ipin Jobu 27

Wo Jobu 27:14 ni o tọ