5 Kí á má rí i, n kò jẹ́ pè yín ní olóòótọ́;títí di ọjọ́ ikú mi ni n óo dúró lórí ọ̀rọ̀ mi,pé mo wà lórí àre.
Ka pipe ipin Jobu 27
Wo Jobu 27:5 ni o tọ