Jobu 32:6 BM

6 Ó ní,“Àgbàlagbà ni yín, ọmọde sì ni mí,nítorí náà ni ojú fi ń tì mí,tí ẹ̀rù sì ń bà mí láti sọ èrò ọkàn mi.

Ka pipe ipin Jobu 32

Wo Jobu 32:6 ni o tọ