16 Jobu kàn ń la ẹnu,ó sì ń sọ̀rọ̀ lásán ni.Ọ̀rọ̀ rẹ̀ pọ̀, ṣugbọn kò mú ọgbọ́n lọ́wọ́.”
Ka pipe ipin Jobu 35
Wo Jobu 35:16 ni o tọ