Jobu 36:11 BM

11 Bí wọ́n bá gbọ́ràn, tí wọ́n sì sìn ín,wọn yóo lo ọjọ́ ayé wọn pẹlu ìdẹ̀rùn,wọn yóo ṣe ọ̀pọ̀ ọdún ninu ìgbádùn.

Ka pipe ipin Jobu 36

Wo Jobu 36:11 ni o tọ