Jobu 36:15 BM

15 A máa lo ìpọ́njú àwọn tí à ń pọ́n lójú láti gbà wọ́n là,a sì máa lo ìdààmú wọn láti ṣí wọn létí.

Ka pipe ipin Jobu 36

Wo Jobu 36:15 ni o tọ