Jobu 38:41 BM

41 Ta ní ń wá oúnjẹ fún àwọn ẹyẹ ìwò,nígbà tí àwọn ọmọ wọn bá kígbe sí Ọlọrun,tí wọ́n sì ń káàkiri tí wọn ń wá oúnjẹ?

Ka pipe ipin Jobu 38

Wo Jobu 38:41 ni o tọ