Jobu 42:16 BM

16 Lẹ́yìn náà Jobu tún gbé ogoje (140) ọdún sí i láyé, ó rí àwọn ọmọ ati àwọn ọmọ-ọmọ rẹ̀ títí dé ìran kẹrin.

Ka pipe ipin Jobu 42

Wo Jobu 42:16 ni o tọ