1. Kro 11:20 YCE

20 Ati Abiṣai arakunrin Joabu, on li olori ninu awọn mẹta: nitoriti o gbé ọ̀kọ rẹ̀ soke si ọ̃dunrun o pa wọn, o si ni orukọ ninu awọn mẹta.

Ka pipe ipin 1. Kro 11

Wo 1. Kro 11:20 ni o tọ