1. Kro 12:15 YCE

15 Wọnyi li awọn ti o gòke odò Jordani li oṣù ekini, nigbati o kún bò gbogbo bèbe rẹ̀; nwọn si le gbogbo awọn ti o wà li afonifoji ninu ila-õrùn, ati niha iwọ-õrùn.

Ka pipe ipin 1. Kro 12

Wo 1. Kro 12:15 ni o tọ