1. Kro 12:23 YCE

23 Eyi ni iye awọn enia na ti o hamọra tan fun ogun, ti nwọn si tọ̀ Dafidi wá si Hebroni, lati pa ijọba Saulu da si ọdọ rẹ̀ gẹgẹ bi ọ̀rọ Oluwa.

Ka pipe ipin 1. Kro 12

Wo 1. Kro 12:23 ni o tọ