1. Kro 12:33 YCE

33 Ninu ti Sebuluni, iru awọn ti o jade lọ si ogun ti o mọ̀ ogun iwé, pẹlu gbogbo ohun èlo ogun, ẹgbamẹ̃dọgbọn; ti nwọn kì ifi iye-meji tẹgun.

Ka pipe ipin 1. Kro 12

Wo 1. Kro 12:33 ni o tọ