1. Kro 13:13 YCE

13 Bẹ̃ni Dafidi kò mu apoti ẹri na bọ̀ si ọdọ ara rẹ̀ si ilu Dafidi, ṣugbọn o gbé e ya si ile Obed-Edomu ara Gitti.

Ka pipe ipin 1. Kro 13

Wo 1. Kro 13:13 ni o tọ