1. Kro 15:13 YCE

13 Nitoriti ẹnyin kò rù u li akọṣe, ni Oluwa Ọlọrun wa fi ṣe ẹ̀ya si wa li ara, nitori awa kò wá a bi o ti yẹ.

Ka pipe ipin 1. Kro 15

Wo 1. Kro 15:13 ni o tọ