1. Kro 15:25 YCE

25 Bẹ̃ni Dafidi ati awọn agbagba Israeli, ati awọn olori ẹgbẹgbẹrun, lọ lati gbe apoti ẹri majẹmu Oluwa jade ti ile Obed-Edomu gòke wá pẹlu ayọ̀.

Ka pipe ipin 1. Kro 15

Wo 1. Kro 15:25 ni o tọ