1. Kro 16:42 YCE

42 Ati pẹlu wọn Hemani ati Jedutuni pẹlu ipè ati kimbali fun awọn ti yio ma pariwo, ati pẹlu ohun èlo orin Ọlọrun. Awọn ọmọ Jedutuni li awọn adena.

Ka pipe ipin 1. Kro 16

Wo 1. Kro 16:42 ni o tọ