13 O si fi ẹgbẹ-ogun si Edomu: ati gbogbo awọn ara Edomu si di iranṣẹ Dafidi. Bayi li Oluwa ngbà Dafidi nibikibi ti o ba nlọ.
Ka pipe ipin 1. Kro 18
Wo 1. Kro 18:13 ni o tọ