1. Kro 2:23 YCE

23 Ṣugbọn Geṣuri, ati Aramu, gbà ilu Jairi lọwọ wọn, pẹlu Kenati, ati ilu rẹ̀: ani ọgọta ilu. Gbogbo wọnyi ni awọn ọmọ Makiri baba Gileadi.

Ka pipe ipin 1. Kro 2

Wo 1. Kro 2:23 ni o tọ