1. Kro 21:14 YCE

14 Bẹ̃ li Oluwa ran ajakalẹ arun si Israeli: awọn ti o ṣubu ni Israeli jẹ ẹgbã marundilogoji enia.

Ka pipe ipin 1. Kro 21

Wo 1. Kro 21:14 ni o tọ