1. Kro 24:5 YCE

5 Bayi li a fi iṣẹkeké pin wọn, iru kan mọ ikeji pẹlu; nitori awọn olori ibi mimọ́, ati olori ti Ọlọrun wà ninu awọn ọmọ Eleasari, ati ninu awọn ọmọ Itamari.

Ka pipe ipin 1. Kro 24

Wo 1. Kro 24:5 ni o tọ