1. Kro 25:5 YCE

5 Gbogbo awọn wọnyi li awọn ọmọ Hemani, woli ọba ninu ọ̀rọ Ọlọrun, lati ma gbé iwo na soke. Ọlọrun si fun Hemani li ọmọkunrin mẹrinla ati ọmọbinrin mẹta.

Ka pipe ipin 1. Kro 25

Wo 1. Kro 25:5 ni o tọ