1. Kro 25:9 YCE

9 Iṣẹkeké ekini si jade wá fun Asafu si Josefu: ekeji si Gedaliah, ẹniti on pẹlu awọn arakunrin rẹ̀ ati awọn ọmọ rẹ̀, jẹ mejila:

Ka pipe ipin 1. Kro 25

Wo 1. Kro 25:9 ni o tọ