1. Kro 27:24 YCE

24 Joabu ọmọ Seruiah bẹ̀rẹ si ikà wọn, ṣugbọn kò kà wọn tan, nitori ibinu ṣubu lu Israeli nitori na; bẹ̃ni a kò fi iye na sinu iwe Kronika ti Dafidi ọba.

Ka pipe ipin 1. Kro 27

Wo 1. Kro 27:24 ni o tọ