1. Kro 29:14 YCE

14 Ṣugbọn tali emi, ati kili awọn enia mi, ti a fi le ṣe iranlọwọ tinutinu bi iru eyi? nitori ohun gbogbo ọdọ rẹ ni ti wá, ati ninu ohun ọwọ rẹ li awa ti fi fun ọ.

Ka pipe ipin 1. Kro 29

Wo 1. Kro 29:14 ni o tọ