1. Kro 29:25 YCE

25 Oluwa si gbé Solomoni ga gidigidi li oju gbogbo Israeli, o si fi ọlá nla ọba fun u bi iru eyi ti kò wà fun ọba kan ṣaju rẹ̀ lori Israeli.

Ka pipe ipin 1. Kro 29

Wo 1. Kro 29:25 ni o tọ