1. Kro 29:29 YCE

29 Njẹ iṣe Dafidi ọba, ibẹ̀rẹ ati ikẹhin, kiyesi i, a kọ ọ sinu iwe Samueli ariran, ati sinu iwe itan Natani woli, ati sinu iwe itan Gadi ariran.

Ka pipe ipin 1. Kro 29

Wo 1. Kro 29:29 ni o tọ