1. Kro 3:1 YCE

1 WỌNYI li awọn ọmọ Dafidi, ti a bi fun u ni Hebroni; akọbi Amnoni, lati ọdọ Ahinoamu ara Jesreeli; ekeji Danieli, lati ọdọ Abigaili ara Karmeli;

Ka pipe ipin 1. Kro 3

Wo 1. Kro 3:1 ni o tọ