1. Kro 6:60 YCE

60 Ati lati inu ẹ̀ya Benjamini; Geba pẹlu ìgberiko rẹ̀, ati Alemeti pẹlu ìgberiko rẹ̀, ati Anatoti pẹlu ìgberiko rẹ̀. Gbogbo ilu wọn ni idile wọn jẹ ilu mẹtala.

Ka pipe ipin 1. Kro 6

Wo 1. Kro 6:60 ni o tọ