1. Kro 6:62 YCE

62 Ati fun awọn ọmọ Gerṣomu ni idile wọn, lati inu ẹ̀ya Issakari, ati inu ẹ̀ya Aṣeri, ati lati inu ẹ̀ya Naftali, ati lati inu ẹ̀ya Manasse ni Baṣani, ilu mẹtala.

Ka pipe ipin 1. Kro 6

Wo 1. Kro 6:62 ni o tọ