1. Kro 6:65 YCE

65 Nwọn si fi keké fi ilu wọnyi ti a da orukọ wọn fun ni lati inu ẹ̀ya awọn ọmọ Juda, ati lati inu ẹ̀ya awọn ọmọ Simeoni, ati lati inu ẹ̀ya awọn ọmọ Benjamini.

Ka pipe ipin 1. Kro 6

Wo 1. Kro 6:65 ni o tọ