1. Kro 7:11 YCE

11 Gbogbo awọn wọnyi ọmọ Jediaeli, nipa olori awọn baba wọn, akọni alagbara enia, jẹ ẹgbãjọ o le ẹgbẹfa ọmọ-ogun, ti o le jade lọ si ogun.

Ka pipe ipin 1. Kro 7

Wo 1. Kro 7:11 ni o tọ