Jóòbù 16:12 BMY

12 Mo ti jókòó jẹ́ẹ́, ṣùgbọ́n ó fà mí já;ó sì dì mí ọrùn mú, ó sì gbọ̀nmí túútúú, ó sì gbé mi kalẹ̀ ṣe àmì—ìtàfàsí rẹ̀.

Ka pipe ipin Jóòbù 16

Wo Jóòbù 16:12 ni o tọ