Jóòbù 30:1 BMY

1 “Ṣùgbọ́n nísinsin yìí,àwọn tí mo gbà ní àbúrò ń fi míṣe ẹlẹ́yà, baba ẹni tí èmi kẹ́gànláti tò pẹ̀lú àwọn ajá agbo-ẹran mi.

Ka pipe ipin Jóòbù 30

Wo Jóòbù 30:1 ni o tọ