Jóòbù 32:12 BMY

12 Àní mo fíyèsí yín tinútinú; sìkíyèsí i, kò sí ẹnìkan nínú yín tí ó le já Jóòbù ní irọ́, tàbí tí ó lèdá a lóhùn àríyànjiyàn rẹ̀!

Ka pipe ipin Jóòbù 32

Wo Jóòbù 32:12 ni o tọ