26 Ó kọlù wọ́n nítorí ìwàbúburú wọn níbi tí àwọn ẹlòmìíràn rí i,
27 nítorí pé wọ́n padà sẹ́yìndà sí i,wọn kò sì fi yè sí ipa ọ̀nà rẹ̀ gbogbo,
28 kí wọn kí ó sì mú igbe ẹkúnàwọn tálákà lọ dé ọ̀dọ̀ rẹ̀, òunsì gbọ́ igbe ẹkún aláìní
29 ṣùgbọ́n nígbà tí ó bá dákẹ́ síbẹ̀, ta ni yóò dá lẹ́bi? Nígbà tí ó bápa ojú rẹ̀ mọ́, ta ni yóò lè rí i?Bẹ́ẹ̀ ni ó ṣe é orilẹ̀ èdè tàbi sí ènìyàn kan ṣoṣo;
30 Kí àgàbàgebè kí ó má báà jọbakí wọn kí ó má di ìdẹ̀wò fún ènìyàn.
31 “Nítorí pé ẹnìkan ha lè wí fúnỌlọ́run pé, èmi jẹ̀bí; èmi kò sì ní ṣẹ̀ mọ́?
32 Èyí tí èmi kò rí ìwọ fi kọ́ mi bimo bá sì dẹ́sẹ̀ èmi kì yóò ṣe bẹ́ẹ̀ mọ́.