Jóòbù 7:11 BMY

11 “Nítorí náà èmi kì yóò pa ẹnu mi mọ́,èmi yóò máa sọ nínú ìrora ọkàn mi,èmí yóò máa ṣe ìráhùn nínú kíkorò ọkàn mi.

Ka pipe ipin Jóòbù 7

Wo Jóòbù 7:11 ni o tọ