Jobu 19:8 BM

8 Ọlọrun ti dí ọ̀nà mọ́ mi, kí n má baà kọjá,ó mú ọ̀nà mi ṣókùnkùn.

Ka pipe ipin Jobu 19

Wo Jobu 19:8 ni o tọ