Jobu 5:15 BM

15 Ṣugbọn Ọlọrun gba aláìníbaba kúrò lọ́wọ́ wọn,ó gba àwọn aláìní kúrò lọ́wọ́ àwọn alágbára.

Ka pipe ipin Jobu 5

Wo Jobu 5:15 ni o tọ