1. Kro 12:1 YCE

1 WỌNYI si li awọn ti o tọ̀ Dafidi wá si Siklagi, nigbati o fi ara rẹ̀ pamọ, nitori Saulu ọmọ Kiṣi: awọn wọnyi si wà ninu awọn akọni ti nṣe oluranlọwọ ogun na.

Ka pipe ipin 1. Kro 12

Wo 1. Kro 12:1 ni o tọ