1. Kro 19:18 YCE

18 Ṣugbọn awọn ara Siria sá niwaju Israeli, Dafidi si pa ẹ̃dẹgbarin enia ninu awọn ara Siria ti o wà ninu kẹkẹ́, ati ọkẹ-meji ẹlẹsẹ, o si pa Ṣofaki olori ogun na.

Ka pipe ipin 1. Kro 19

Wo 1. Kro 19:18 ni o tọ